Nibi isinku Kayode Esho, Gomina Aregbesola ro eka idajo
Transkript
Nibi isinku Kayode Esho, Gomina Aregbesola ro eka idajo
E ba wa dele E mo nipa wa E polowo oja yin AKEDE Agbaye Idanileko ALAROYE Bi o ba fe ba wa sise Adiresi wa Nibi isinku Kayode Esho, Gomina Aregbesola ro eka idajo lati maa sagbekale idajo nilana ofin Awon Iroyin to se koko Bisi Adesoye, Ilesa Fayose derin-in peeke G awon olokada l’Ekiti omina ipinleô O·sôun, O·gbeôni Rauf Adesoôji Areôgbeôsôoôla gbosôuba fun Oloogbe Onidajoô Kayoôde Eôshoô geôgeô bii eôni to jeô olotitoô, oômoôluabi ati eôni to mu eto idajoô goke agba ni orileô-ede yii. O·gbeôni Areôgbeôsôoôla soôroô yii di mimoô nibi ayeôyeô eto isinku oloogbe naa to waye n’Ileôsôa, loôjoô Eôti, Abiola Ajimobi tipinle Oyo, igbakeji Gomina ipinle Osun, Arabinrin Titilayo Fraide, oôseô to koôja. Laoye-Tomori, Iyawo Oloogbe Onidajo Kayode Esho, Helena, ati aburo Ninu oôroô Gomina lo ti roô Oloogbe, Eni-Owo Ladipo Esho, nibi apejo pataki ti won se fun Oloogbe ni kootu giga tilu Ibadan gbogbo awoôn ti woôn wa leôka idajoô lorileô-ede yii pata lati ri oloogbe yii geôgeô bii awokoôsôe eeyan kan to duro lori lilo ofin ninu idajoô reô. Oni gbogbo idajoô Oloogbe Eôshoô lo jeô ohun to sôe e toôkasi fawoôn agbeôjoôro gbogbo to wa ni lorileô ede yii, nitori gbogbo reô lo jeô eyi to gbekaleô loôna ofin. Nigba ti Bisôoôoôbu eôkun Ilesôa,Rt. Rev Dr. Olubayoô Sôowale, n soôroô nibi iboji oloogbe naa lo ti soô pe Oloogbe Kayoôde Eôshoô jeô onigbagboô eeyan ti ko ko ohun aye maya. Oni ijoô Anglican ko ni i gbagbe reô nipa bo sôe fi ile ijoôsin to koô sinu oôgba ile reô lopopona Oke-Omiru, Ilesôa, ta ijoô naa loôreô. Bakan naa ni asôiwaju ijoô naa soô pe ipa ribiribi ti Onidajoô yii ti ko laye, ati bo sôe sôe beôbeô ninu isôeô to yan laayo ni ko ni i jeô ki awoôn eeyan gbagbe eô laelae. Ninu oôroô isôiri ti Bisoôoôbu ba awoôn eeyan soô loôjoô naa lo ti roô gbogbo awoôn ti woôn wa ni ilana eto idajoô atawoôn agbeôjoôro pata lati ma sôe jeô ki ilana ti oloogbe fi leleô pareô, paapaa juloô nipa eto idajoô ati ti eôka agbeôjoôro lorileô-ede yii. Lasiko tawoôn oômoô meji ti oloogbe yii fi sileô n bu eeru fun eeru, erupeô fun erupeô ni omije n jade loju woôn, iyawo reô ati oôgoôoôroô awoôn eeyan ni woôn si peju seti iboji lati sôe eôyeô ikeôyin fun un. Iduunu subu layo fawon osise nipinle Oyo, orisiirisii ajemonu nijoba fun won Eto eko nijoba yoo nawo le lori julo lodun to n bo nipinle Kwara N’Ilesa, won fesun agbere kan pasito, lo ba ni ise esu ni, o ti foju bale-ejo Owo awon eleto aabo ilu te awon to n ji epo bentiroolu wa nipinle Ogun Keshi gbe oruko awon agbaboolu jade fun idije Nations Cup E tun pade wa lori ero E wa awon iroyin wa